Independent Content Services (ICS) jẹ́ aléwájú ẹ̀rọ alátagbà pàtàkì fún àgbáyé. A máa n ṣẹda ogúnlọ́gọ̀ ìtàn ojojúmọ́, àfihàn, àti àwòtẹ́lẹ̀, pẹ̀lú ọ̀pọ̀lọpọ̀ wákàtí ìwé ohùn tí a gbà sílẹ̀ láàyè ní oríṣiríṣi èdè tí o fẹẹ tó bíi mẹ́ẹ̀dọ́gbọ̀n tàbí jùbẹ́ lọ lati lè fàyè gba àwọn oníbara wa lati ibi kíbi. ICS tun máa n ṣe ìgbélárugẹ àwọn ọjá àti iṣẹ́ tó rọ̀ mọ.