Nípa Wa

A dáa ilé iṣẹ́ Independent Content Services Limited (ICS) lẹ̀ ní ọdún 2002. Ilé iṣẹ́ na gba àwọn òṣìṣẹ́ tí wọ́n súnmọ́ ra wọn, tí wọ́n sì kójú òṣùnwọ̀n, àti àwọn oníròyìn olómìnira, pẹ̀lú àwọn alámọ̀já olùrànlọ́wọ́, a sì jẹ́ aṣíwájú nínú ìpèsè akóónú, ìkéde, ìpolongo, àti iṣẹ́ tí ó rọ̀ mọ.

Ìbáṣepọ̀ owò ṣe pàtàkì sí wa, bẹẹ na ni àláfíà àti ìfọkànbalẹ̀ àwọn òṣìṣẹ́ wa lórí iṣẹ́, a sì máa n làkàkà láti ri wípé àyíká ibiṣẹ́ wà ní ìdùnnú.

Inú wa yóò dùn láti gbọ́ ọ̀rọ̀ lẹ́nu ẹnikẹni tí ó bá nílò ìrànlọ́wọ́ wa.