Ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́

Tí ẹ bá ń wá láti dá ilé isẹ́ tẹlifisàn lórí ẹ̀rọ ayélujára, ilé iṣẹ́ ẹ̀rọ rédíò, tàbí wiwo ètò kan láàyè, a lè ràn yín lọ́wọ́.

Pẹ̀lú ọ̀pọ̀lọpọ̀ àkójọpọ̀ àwọn olùgbóhùnsáfẹ́fẹ́ àti àwọn olùṣe, awà ní ipò tí ó dára láti ṣe èyí ní àṣeyọrí, yálà tí ó bá tóbi tàbí tí ó bá kéré.

A lè ṣètò rédíò tàbí tẹlifísàn oníìṣẹ́jú mẹ́ta, tí kò ní náa yín lówó, ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ àwíyé lórí onírurú eré ìdárayá, igbóhùnsáfẹ́fẹ́ olówó ńlá tí yóò nílò ìmọ́lẹ̀, ìtàgé àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ pẹ̀lú ìrànlọ́wọ́ àwọn alámọ̀já wa.