Àwíyé

ICS jẹ́ amòye fún ìpèsè àwíyé àti àsọkiri pàapàa nígbà ìṣẹ̀lẹ̀ eré ìdárayá.

A lè ṣe èyí yálà nípasẹ̀ àìlèlo ẹ̀rọ ayélujára pẹ̀lú òmìnira, níbitì àwọn olùgbóhùnsáfẹ́fẹ́ wa yóò lo àwòrán gẹ́gẹ́ bi ọ̀nà láti lè pèsè ojúlówó ìwé ohùn, tàbí kí a ṣe ìfọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú àwọn tí ó lẹ́tọ láti pèsè àwọn àwòtẹ́lẹ̀ fún wíwò gbogbogbò.

Fún àwọn ònṣèwé, àwíyé ṣe pàtàkì láti lè fẹ ìrírí ìkíle lójú àti láti ṣí wọn lórí nígbà tí wọ́n bá n díje, eléyì si maa n fa kí àwọn ètò orí fóònù àti ti rédíò lókìkí.

A máa n ṣe àwíyé òmìnira lórí gbogbo ìdíje bọ́ọ̀lù aláfẹsẹ̀gbá ti àwọn òyìnbo àti ti àwọn aṣájú, pẹ̀lú àwọn ìdíje bọ́ọ̀lù aláfẹsẹ̀gbá pàtàkì lágbayé. A sì tún jẹ́ olùpínfúnni lábẹ́ oyè àwíyé eré ìdíje ti ẹṣin sísá ní ìlú UK, eléyi tí a lè pèsè ní èdèkédè, láti ara ìbáṣepọ̀ wa pẹ̀lú GBI.