Akóónú

ICS jẹ́ aṣẹ̀dá ojúlówó akóónú, tí wọ́n sì mọ ìpèsè àwòtẹ́lẹ́ ní ìwé ohùn àti fídìo lámọ̀já, àti iṣẹ́ tí ó rọ̀ mọ.

Nítorí aní ogúnlọ́gọ̀ ònkọ̀wé àti olùgbóhùnsáfẹ́fẹ́ ní àrọ́wọ́tó wa ní oríṣiríṣi agbègbè, a máa n ṣe ìpèsè akóónú lórí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àkọ́lé fún gbogbo ipasẹ̀ ìfifúni níròyìn ní ìlànà tí ó bójú mu fún àwọn oníbara wa.