Èdè

A máa n pèsè iṣẹ́ ògbìfọ̀, olóòtú, àwíyé láàyè, ìfọwọ́sowọ́pọ̀ tí ó dán mọ́rán, ilukoro, àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lọ ní èdè tí ẹ bá fẹ́.

Àwọn èdè tí a pèsè sílẹ̀ nísisíyi nì wọ̀nyí:

Arabic, Bulgarian, Chinese (àbáláyé àti ti ìyànjú), Czech, Danish, Dutch, English, Finnish, French, German, Greek, Hebrew, Hungarian, Italian, Norweigian, Portugese (ti Òyìnbó àti ti Bràsílìa), Polish, Romanian, Russian, Slovakian, Spanish (ti òyìnbó àti ti òyìnbó látìnì), Swedish, àti Thai, a sì máa ń kọ ní ọ̀nà ìbílẹ̀ fún àwọn òyìnbó àréwá (North America), Australia/New Zealand, Ireland, àti South Africa.

A tún ní àwọn ẹgbẹ́ tí ó wà ní àwọn ọ́fíìsì ní gbogbo igun àgbáyé tí wọ́n lè ṣe ìwádi òye ìlúkílù, wọn ó sì pèsè òye tí ó lẹ́kùnrẹ́rẹ́ fún akóónú àti ìpolongo.