Ìsìn ògbifọ̀

ICS máa ń ṣètò ògbìfọ̀ ọlọ́jọ̀gbọ́n àti ṣíṣe àtúnkà àwọn onírurú èdè fún àwọn ilé iṣé àti àwọn ènìyàn. A máa ń ṣe ògbìfọ̀ ìwé àti aláǹtakùn fún gbogbo ìpín ilé iṣẹ́, a sì tún lè ṣètò àkóónú ní oríṣiríṣi ètò kíkọ bí ẹ bá ṣe fẹ́.

A sì tún máa ń ṣiṣẹ́ pẹ̀lú àwọn oníbárà wa láti pèsè àkóónú fún àwọn tí ó rọ̀mọ́ ìlú pàtàkì àti ṣíṣe ìpolongo títà fún àwọn agbègbè ìlú.

Àwọn àkójọpọ̀ òjọ̀gbọ́n wa nímọ̀ pé oníbárà lè nílò iṣẹ́ wọn ní pàjáwìrì, nítorí nàa, wọ́n lè ṣe ìsìn tí ó rọrùn, tí ó ṣeéṣe, tí ó sì jẹ́ sí ìfọkànbalẹ̀ oníbárà wa ní iye tí ó ní àdéhùn.