Àfaramọ́

Títà aláfaramọ́ lè jẹ́ ọ̀nà tí ó rọrùn tí kò sì wọ́n rárá láti lè rí àwọn oníbara titun fún òwò rẹ̀. A ní àwọn onípolongo aláfaramọ́ tí óní ìrírí tí wọ́n sì mọ ìṣẹ́ dé ojú àmì tí wọ́n lè ṣe àmójútó, tí wọ́n lè mú ìlọsíwájú bá àwọn àfaramọ́ ti tẹ̀yìn wá àti pẹ̀lúpẹ̀lú dá ètò àfaramọ́ titun sílẹ̀.

Àwọn àkójọpọ̀ ènìyàn wa tí wọ́n kójú òṣùnwọ̀n jẹ́ amòye ní gbígba àti ṣíṣe àmójútó àfaramọ́, wọ́n sì ní agbára láti lè bá ọ̀pọ̀lọpọ̀ alábápín aláǹtakùn ṣe, tí yóò ràn yín lọ́wọ́ láti lè dá àti láti mú ìdàgbàsókè bá ìpílẹ̀ àfaramọ́ tìrẹ.

Ní ICS, a lè mú ìsìn bá ohun tí ẹ bá fẹ́ a ó sì ṣe àmójútó ìpolówó àfaramọ lẹ́kúnrẹ́rẹ́ tàbí ní àbọ̀, bí ó bá ṣe wùn yín. A lè ṣe onírurú èdè àti oríṣiríṣi ìlú.

Alámọ̀já ni wá ní onírurú ilé isẹ́ bíi eré, alámúdájú, ìnáwó, ìránṣẹ́sí, ìrìn àjò, eré ìdárayá, àti àyọ́tà. A lè ṣiṣẹ́ lóri ìgbèrò ọlọ́jó kúkurú àti ọlọ́jọ́ gígùn pẹ̀lú ìfọkànbalẹ̀ wípé a ó ṣe iṣẹ́ náà dé ojú àmì láì náa yín ní owó púpọ̀.

A ti ṣiṣẹ́ aláṣeyọrí ńlá lórí ìpolongo ọlọ́jọ́ pípẹ́ fún àwọn oníbára àdáni àti ìbáṣepọ̀ tí ó lágbára, òye ilé iṣẹ́ àfaramọ́, àti ìsìn títà aláfaramọ́ fún oníbára kọ̀ọ̀ kan.