Alágbéká

Gẹ́gẹ́ bí jíjáwé lórí ẹ̀rọ alágbéká ìgbàlódé ti lọ sókè si, àwọn ètò orí fóònù sì ti gbòòrò nínú ìwúlò àti ìmóríyá wọn, ICS wa ní ipò tí ó dára láti pèsè akóónú ńlá àti ọ̀nà àbáyọ.

A máa n ṣẹ̀dá, a sì máa ń ṣe ìfikún eré ṣíṣe, eré ìdárayá, ìròyìn àti akóónú tí ó wà fún ìkéde lórí alágbéká, láfikún a máa n ṣẹ̀dá ètò orí fóònù, kọ ipò alágbéká, àti gbígbé ìpolongo ọjà lórí alágbéká lárugẹ.